Orin Dafidi 1:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Àwọn eniyan burúkú kò rí bẹ́ẹ̀,ṣugbọn wọ́n dàbí fùlùfúlù tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ.

5. Nítorí náà àwọn eniyan burúkú kò ní rí ìdáláre,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ kò ní le wà ní àwùjọ àwọn olódodo.

6. Nítorí OLUWA ń dáàbò bo àwọn olódodo,ṣugbọn àwọn eniyan burúkú yóo ṣègbé.

Orin Dafidi 1