Orin Dafidi 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà àwọn eniyan burúkú kò ní rí ìdáláre,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ kò ní le wà ní àwùjọ àwọn olódodo.

Orin Dafidi 1

Orin Dafidi 1:1-6