Ọbadaya 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ náà, ni n óo pa àwọn ọlọ́gbọ́n run ní Edomu,òye wọn yóo sì di òfo ní òkè Esau.

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:1-17