Ọbadaya 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n bá ọ dá majẹmu ti tàn ọ́ jẹ,wọ́n sì ti lé ọ títí dé ààlà ilẹ̀ rẹ;àwọn tí ẹ jọ ń gbé ní alaafia tẹ́lẹ̀ ti di ọ̀tá rẹ;àwọn ọ̀rẹ́ tí o gbẹ́kẹ̀lé ti dẹ tàkúté sílẹ̀ dè ọ́,o kò sì mọ̀.

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:1-14