Ọbadaya 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí àwọn olè bá wá bá ọ lóru,tí àwọn ọlọ́ṣà bá wá ká ọ mọ́lé lọ́gànjọ́,ṣé wọn kò ní hàn ọ́ léèmọ̀?Ṣebí ohun tí wọ́n bá fẹ́ ninu ẹrù rẹ ni wọn óo kó?Bí àwọn tí wọn ń kórè àjàrà bá wá sọ́dọ̀ rẹ,ṣebí wọn a máa fi díẹ̀ sílẹ̀?

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:1-14