Ọbadaya 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o tilẹ̀ fò lọ sókè bí ẹyẹ idì,tí ó tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí ààrin àwọn ìràwọ̀,láti òkè náà ni n óo ti fà ọ́ lulẹ̀.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:1-11