Ọbadaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún Edomu pé, “Wò ó, n óo sọ ọ́ di yẹpẹrẹ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù;gbogbo ayé pátá ni yóo máa fi ọ́ ṣẹ̀sín.

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:1-8