Nọmba 32:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Makiri tíí ṣe ẹ̀yà Manase gbógun ti àwọn ará Amori tí ó wà ní Gileadi, wọ́n lé wọn jáde, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn.

Nọmba 32

Nọmba 32:36-42