Nọmba 32:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebo, Baali Meoni (wọ́n yí orúkọ ìlú yìí pada) ati Sibima. Wọ́n sì fún àwọn ìlú tí wọn tún kọ́ ní orúkọ mìíràn.

Nọmba 32

Nọmba 32:28-39