Nọmba 30:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni ìlànà tí OLUWA pa láṣẹ fún Mose láàrin ọkọ ati aya ati láàrin baba ati ọmọ rẹ̀ obinrin, tí ń gbé ninu ilé rẹ̀.

Nọmba 30

Nọmba 30:14-16