Nọmba 26:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Bẹnjamini ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Bela, ìdílé Aṣibeli, ìdílé Ahiramu;

Nọmba 26

Nọmba 26:29-41