Nọmba 26:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Efuraimu jẹ́ ẹgbaa mẹrindinlogun ó lé ẹẹdẹgbẹta (32,500). Àwọn ni ọmọ Josẹfu ní ìdílé-ìdílé.

Nọmba 26

Nọmba 26:36-43