Nọmba 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Òjò yóo rọ̀ fún Israẹli ní àkókò rẹ̀,omi yóo jáde láti inú agbè rẹ̀;àwọn ohun ọ̀gbìn rẹ̀ yóo sì rí omi mu.Ọba wọn yóo lókìkí ju Agagi lọ,ìjọba rẹ̀ ni a óo sì gbéga.

Nọmba 24

Nọmba 24:5-13