Nọmba 24:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dàbí àfonífojì tí ó tẹ́ lọ bẹẹrẹ,bí ọgbà tí ó wà lẹ́bàá odò.Ó dàbí àwọn igi aloe tí OLUWA gbìn,ati bí igi kedari tí ó wà lẹ́bàá odò.

Nọmba 24

Nọmba 24:1-16