Nọmba 22:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́ẹ̀kan sí i, angẹli náà lọ siwaju, ó dúró ní ọ̀nà tóóró kan níbi tí kò sí ààyè rárá láti yà sí.

Nọmba 22

Nọmba 22:24-30