Nọmba 22:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà rí i, ó fún ara rẹ̀ mọ́ ògiri, ẹsẹ̀ Balaamu sì fún mọ́ ògiri pẹlu, Balaamu bá tún lù ú.

Nọmba 22

Nọmba 22:18-30