Nọmba 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò, wọ́n lọ pa àgọ́ wọn sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní òdìkejì Jọdani tí ó kọjú sí Jẹriko.

Nọmba 22

Nọmba 22:1-2