Nọmba 21:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli pa Ogu ati àwọn ọmọ rẹ̀ ati gbogbo eniyan rẹ̀. Wọn kò dá ẹnìkan sí, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn.

Nọmba 21

Nọmba 21:28-35