Ṣugbọn nisinsinyii, a ti pa ìrandíran wọn run,láti Heṣiboni dé Diboni,láti Naṣimu dé Nofa lẹ́bàá Medeba.”