Ẹ̀yin ará Moabu, ẹ gbé! Ẹ di ẹni ìparun, ẹ̀yin ọmọ oriṣa Kemoṣi!Ó ti sọ àwọn ọmọkunrin yín di ẹni tí ń sálọ fún ààbò;ó sì sọ àwọn ọmọbinrin yín di ìkógunfún Sihoni ọba àwọn ará Amori.