Nehemaya 7:72 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí àwọn eniyan yòókù fi sílẹ̀ ni ọ̀kẹ́ kan (20,000) ìwọ̀n diramu wúrà ati ẹgbaa (2,000) ìwọ̀n mina fadaka ati aṣọ àwọn alufaa mẹtadinlaadọrin.

Nehemaya 7

Nehemaya 7:64-73