Nehemaya 7:71 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan ninu àwọn baálé baálé fi ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùnwọ̀n diramu wúrà sí ilé ìṣúra ati ẹgbọkanla (2,200) òṣùnwọ̀n mina fadaka.

Nehemaya 7

Nehemaya 7:63-73