Nehemaya 12:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi wẹ ara wọn mọ́, wọ́n sì ṣe ìwẹ̀mọ́ fún àwọn eniyan ati àwọn bodè ati odi ìlú náà.

Nehemaya 12

Nehemaya 12:26-35