Nehemaya 12:29 BIBELI MIMỌ (BM)

bákan náà ni láti Betigiligali ati láti ẹkùn Geba, ati Asimafeti, nítorí pé àwọn akọrin kọ́ ìletò fún ara wọn ní agbègbè Jerusalẹmu.

Nehemaya 12

Nehemaya 12:19-34