Nahumu 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Pupa ni asà àwọn akọni rẹ̀,ẹ̀wù pupa ni àwọn ọmọ ogun rẹ̀ wọ̀Kẹ̀kẹ́ ogun wọn ń kọ mànàbí ọwọ́ iná;nígbà tí wọ́n tò wọ́n jọ,àwọn ẹṣin wọn ń yan.

Nahumu 2

Nahumu 2:1-4