Mika 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn olukuluku yóo jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀,ati lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, kò sì ní sí ẹni tí yóo dẹ́rùbà wọ́n;nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ó sọ bẹ́ẹ̀.

Mika 4

Mika 4:1-13