Mika 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ṣe ìdájọ́ láàrin ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè,ati láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tí ó lágbára ní ọ̀nà jíjìn réré;wọn yóo fi idà wọn rọ ọkọ́,wọn yóo sì fi ọ̀kọ̀ wọn rọ dòjé;àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,wọn kò sì ní kọ́ ogun jíjà mọ́.

Mika 4

Mika 4:1-11