Matiu 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Èwo ni ó rọrùn jù, láti sọ pé, ‘A dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ ni,’ tabi láti sọ pé, ‘Dìde, kí o máa rìn?’

Matiu 9

Matiu 9:3-15