Matiu 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu mọ èrò inú wọn; ó bá bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ fi ń ro èrò burúkú ninu ọkàn yín?

Matiu 9

Matiu 9:1-13