Matiu 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu rí ọ̀pọ̀ eniyan tí wọ́n yí i ká, ó pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé kí wọn kọjá sí òdìkejì òkun.

Matiu 8

Matiu 8:10-21