Matiu 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Báyìí ni ọ̀rọ̀ tí wolii Aisaya sọ ṣẹ, nígbà tí ó sọ pé, “Òun fúnra rẹ̀ ni ó mú àìlera wa lọ, ó sì gba àìsàn wa fún wa.”

Matiu 8

Matiu 8:13-24