Matiu 27:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu bi wọ́n pé, “Ohun burúkú wo ni ó ṣe?”Ṣugbọn wọ́n túbọ̀ kígbe pé, “Kàn án mọ́ agbelebu.”

Matiu 27

Matiu 27:15-33