Matiu 27:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu wá bi wọ́n pé, “Kí ni ẹ fẹ́ kí n ṣe sí Jesu tí ó ń jẹ́ Mesaya?”Gbogbo wọn dáhùn pé, “Kàn án mọ́ agbelebu.”

Matiu 27

Matiu 27:17-23