Matiu 25:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo jẹ́ àlejò, ẹ kò gbà mí sílé. Mo wà ní ìhòòhò, ẹ kò daṣọ bò mí. Mo ṣàìsàn, mo wà lẹ́wọ̀n, ẹ kò wá wò mí.’

Matiu 25

Matiu 25:36-46