Matiu 25:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí ebi ń pa mí, ẹ kò fún mi ní oúnjẹ jẹ. Òùngbẹ ń gbẹ mí, ẹ kò fún mi ní omi mu.

Matiu 25

Matiu 25:39-46