Matiu 23:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má pe ẹnìkan ní ‘Baba’ ní ayé, nítorí ẹnìkan ṣoṣo ni Baba yín, ẹni tí ó wà ní ọ̀run.

Matiu 23

Matiu 23:8-11