Matiu 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni ẹ má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni pè yín ní ‘Ọ̀gá,’ nítorí ọ̀gá kanṣoṣo ni ẹ ní, òun ni Mesaya.

Matiu 23

Matiu 23:1-16