Matiu 23:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá fi ọ̀run búra, ó fi ìtẹ́ Ọlọrun ati Ọlọrun tí ó jókòó lórí ìtẹ́ náà búra pẹlu.

Matiu 23

Matiu 23:15-31