Matiu 23:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá fi Tẹmpili búra, ohun tí ó wà ninu rẹ̀ ati Ọlọrun tí ó ń gbé inú rẹ̀ ni ó fi búra pẹlu.

Matiu 23

Matiu 23:14-29