Matiu 21:40 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, nígbà tí ẹni tí ó ni ọgbà àjàrà bá dé, kí ni yóo ṣe sí àwọn alágbàro náà?”

Matiu 21

Matiu 21:32-43