Matiu 21:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá mú un, wọ́n tì í jáde kúrò ninu ọgbà àjàrà, wọ́n sì pa á.

Matiu 21

Matiu 21:34-43