Matiu 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pe gbogbo àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin láàrin àwọn eniyan, ó wádìí nípa ibi tí a óo ti bí Kristi lọ́wọ́ wọn.

Matiu 2

Matiu 2:1-6