Matiu 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Hẹrọdu gbọ́, ara rẹ̀ kò balẹ̀, ara gbogbo eniyan ìlú Jerusalẹmu náà kò sì balẹ̀.

Matiu 2

Matiu 2:1-12