Matiu 14:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru sọ fún un pé, “Oluwa, bí ó bá jẹ́ pé ìwọ ni, sọ pé kí n máa rìn bọ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ lójú omi.”

Matiu 14

Matiu 14:20-33