Matiu 14:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹsẹkẹsẹ Jesu sọ fún wọn pé, “Ẹ ṣe ara gírí. Èmi ni. Ẹ má bẹ̀rù!”

Matiu 14

Matiu 14:23-31