Matiu 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkọ̀ ti kúrò ní èbúté, ó ti bọ́ sí agbami. Ìgbì omi wá ń dààmú ọkọ̀, nítorí afẹ́fẹ́ ṣọwọ́ òdì sí wọn.

Matiu 14

Matiu 14:21-34