Matiu 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tú wọn ká tán, ó gun orí òkè lọ gbadura, òun nìkan. Nígbà tí alẹ́ lẹ́, òun nìkan ni ó wà níbẹ̀.

Matiu 14

Matiu 14:15-24