Matiu 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu bá wá, wọ́n gbé òkú rẹ̀ lọ, wọ́n sin ín; wọ́n sì lọ ròyìn fún Jesu.

Matiu 14

Matiu 14:7-22