Matiu 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé orí rẹ̀ wá ninu àwo pẹrẹsẹ, wọ́n gbé e fún ọdọmọbinrin náà. Ó bá lọ gbé e fún ìyá rẹ̀.

Matiu 14

Matiu 14:6-17