Matiu 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin ni a fi àṣírí ìmọ̀ ìjọba ọ̀run hàn, a kò fihan àwọn yòókù wọnyi.

Matiu 13

Matiu 13:1-18